Native Bible

Genesis 23:3 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Abrahamu sì dìde lẹ́gbẹ̀ẹ́ òkú aya rẹ̀, ó sì sọ fún àwọn ará Hiti wí pé,

Genesis 23:3 in English

Genesis 23:3 · Berean Standard Bible

Then Abraham got up from beside his dead wife and said to the Hittites,*

Context

1Sara sì pé ọmọ ọdún mẹ́tàdínláàádóje (127). 2Ó sì kú ní Kiriati-Arba (ìyẹn ní Hebroni) ní ilẹ̀ Kenaani, Abrahamu lọ láti ṣọ̀fọ̀ àti láti sọkún nítorí Sara. 3Abrahamu sì dìde lẹ́gbẹ̀ẹ́ òkú aya rẹ̀, ó sì sọ fún àwọn ará Hiti wí pé, 4“Èmi jẹ́ àtìpó àti àlejò láàrín yín, ẹ ta ilẹ̀ ìsìnkú fún mi kí èmi le sin òkú tí ó kú fún mi sí.” 5Àwọn ọmọ Hiti dá Abrahamu lóhùn pé,

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.