Native Bible

Genesis 23:1 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Sara sì pé ọmọ ọdún mẹ́tàdínláàádóje (127).

Genesis 23:1 in English

Genesis 23:1 · Berean Standard Bible

Now Sarah lived to be 127 years old.

Context

1Sara sì pé ọmọ ọdún mẹ́tàdínláàádóje (127). 2Ó sì kú ní Kiriati-Arba (ìyẹn ní Hebroni) ní ilẹ̀ Kenaani, Abrahamu lọ láti ṣọ̀fọ̀ àti láti sọkún nítorí Sara. 3Abrahamu sì dìde lẹ́gbẹ̀ẹ́ òkú aya rẹ̀, ó sì sọ fún àwọn ará Hiti wí pé,

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.