Native Bible

Genesis 19:23 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Nígbà tí Lọti yóò fi dé ìlú Soari, oòrùn ti yọ.

Genesis 19:23 in English

Genesis 19:23 · Berean Standard Bible

And by the time the sun had risen over the land, Lot had reached Zoar.

Context

21Ó sì wí fún un pé, “Ó dára, mo gba ẹ̀bẹ̀ rẹ. Èmi kì yóò run ìlú náà tí ìwọ sọ̀rọ̀ rẹ̀. 22Tètè! Sálọ síbẹ̀, nítorí èmi kò le ṣe ohun kan àyàfi tí ó bá dé ibẹ̀.” (ìdí nìyí tí a fi ń pe ìlú náà ní Soari). 23Nígbà tí Lọti yóò fi dé ìlú Soari, oòrùn ti yọ. 24Nígbà náà ni Olúwa rọ̀jò iná àti sulfuru* sórí Sodomu àti Gomorra láti ọ̀run lọ́dọ̀ Olúwa wá. 25Báyìí ni ó run àwọn ìlú náà àti gbogbo ilẹ̀ pẹ̀tẹ́lẹ̀, pẹ̀lú gbogbo àwọn tí ó wà ní ìlú ńlá ńlá wọ̀n-ọn-nì àti ohun gbogbo tí ó hù jáde nílẹ̀.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.