Esra 1:10
Ezra 1:10 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ọgbọ̀n àdému wúrà~~30 Irinwó ó lé mẹ́wàá oríṣìí àdému fàdákà mìíràn~~410 Ẹgbẹ̀rún kan àwọn ohun èlò mìíràn~~1,000
Ezra 1:10 in English
Ezra 1:10 · Berean Standard Bible
30 gold bowls, 410 matching silver bowls, and 1,000 other articles.
Context
8Kirusi ọba Persia pàṣẹ fún Mitredati olùṣọ́ ilé ìṣúra láti kó wọn jáde, ó sì kà wọ́n fún Ṣeṣbassari ìjòyè Juda. 9Èyí ni iye wọn.
Ọgbọ̀n àwo wúrà~~30
Ẹgbẹ̀rún àwo fàdákà~~1,000
Àwo ìrúbọ fàdákà mọ́kàndínlọ́gbọ̀n~~29 10Ọgbọ̀n àdému wúrà~~30
Irinwó ó lé mẹ́wàá oríṣìí àdému fàdákà mìíràn~~410
Ẹgbẹ̀rún kan àwọn ohun èlò mìíràn~~1,000 11Gbogbo ohun èlò wúrà àti ti fàdákà ní àpapọ̀ jẹ́ ẹgbẹ̀rún márùn-ún ó lé irinwó (5,400).
Ṣeṣbassari kó gbogbo àwọn nǹkan wọ̀nyí wá pẹ̀lú àwọn ìgbèkùn tí ó gòkè wá láti Babeli sí Jerusalẹmu.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.