Native Bible

Ezra 1:9 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Èyí ni iye wọn. Ọgbọ̀n àwo wúrà~~30 Ẹgbẹ̀rún àwo fàdákà~~1,000 Àwo ìrúbọ fàdákà mọ́kàndínlọ́gbọ̀n~~29

Ezra 1:9 in English

Ezra 1:9 · Berean Standard Bible

This was the inventory: 30 gold dishes,* 1,000 silver dishes, 29 silver utensils,

Context

7Ní àfikún, ọba Kirusi mú àwọn ohun èlò tí ó jẹ́ ti ilé Olúwa jáde wá, tí Nebukadnessari ti kó lọ láti Jerusalẹmu tí ó sì ti kó sí ilé òrìṣà rẹ̀. 8Kirusi ọba Persia pàṣẹ fún Mitredati olùṣọ́ ilé ìṣúra láti kó wọn jáde, ó sì kà wọ́n fún Ṣeṣbassari ìjòyè Juda. 9Èyí ni iye wọn. Ọgbọ̀n àwo wúrà~~30 Ẹgbẹ̀rún àwo fàdákà~~1,000 Àwo ìrúbọ fàdákà mọ́kàndínlọ́gbọ̀n~~29 10Ọgbọ̀n àdému wúrà~~30 Irinwó ó lé mẹ́wàá oríṣìí àdému fàdákà mìíràn~~410 Ẹgbẹ̀rún kan àwọn ohun èlò mìíràn~~1,000 11Gbogbo ohun èlò wúrà àti ti fàdákà ní àpapọ̀ jẹ́ ẹgbẹ̀rún márùn-ún ó lé irinwó (5,400). Ṣeṣbassari kó gbogbo àwọn nǹkan wọ̀nyí wá pẹ̀lú àwọn ìgbèkùn tí ó gòkè wá láti Babeli sí Jerusalẹmu.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.