Esra 1:11
Ezra 1:11 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Gbogbo ohun èlò wúrà àti ti fàdákà ní àpapọ̀ jẹ́ ẹgbẹ̀rún márùn-ún ó lé irinwó (5,400). Ṣeṣbassari kó gbogbo àwọn nǹkan wọ̀nyí wá pẹ̀lú àwọn ìgbèkùn tí ó gòkè wá láti Babeli sí Jerusalẹmu.
Ezra 1:11 in English
Ezra 1:11 · Berean Standard Bible
In all, there were 5,400 gold and silver articles. Sheshbazzar brought all these along when the exiles went up from Babylon to Jerusalem.
Context
9Èyí ni iye wọn.
Ọgbọ̀n àwo wúrà~~30
Ẹgbẹ̀rún àwo fàdákà~~1,000
Àwo ìrúbọ fàdákà mọ́kàndínlọ́gbọ̀n~~29 10Ọgbọ̀n àdému wúrà~~30
Irinwó ó lé mẹ́wàá oríṣìí àdému fàdákà mìíràn~~410
Ẹgbẹ̀rún kan àwọn ohun èlò mìíràn~~1,000 11Gbogbo ohun èlò wúrà àti ti fàdákà ní àpapọ̀ jẹ́ ẹgbẹ̀rún márùn-ún ó lé irinwó (5,400).
Ṣeṣbassari kó gbogbo àwọn nǹkan wọ̀nyí wá pẹ̀lú àwọn ìgbèkùn tí ó gòkè wá láti Babeli sí Jerusalẹmu.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.