Native Bible

Exodus 1:4 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Dani àti Naftali; Gadi àti Aṣeri.

Exodus 1:4 in English

Exodus 1:4 · Berean Standard Bible

Dan and Naphtali; Gad and Asher.

Context

2Reubeni, Simeoni, Lefi àti Juda; 3Isakari, Sebuluni àti Benjamini; 4Dani àti Naftali; Gadi àti Aṣeri. 5Àwọn ìran Jakọbu sì jẹ́ àádọ́rin ní àpapọ̀; Josẹfu sì ti wà ní Ejibiti. 6Wàyí o, Josẹfu àti gbogbo àwọn arákùnrin rẹ̀ àti gbogbo ìran náà kú,

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.