Native Bible

Exodus 1:5 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Àwọn ìran Jakọbu sì jẹ́ àádọ́rin ní àpapọ̀; Josẹfu sì ti wà ní Ejibiti.

Exodus 1:5 in English

Exodus 1:5 · Berean Standard Bible

The descendants of Jacob numbered seventy * in all, including Joseph, who was already in Egypt.

Context

3Isakari, Sebuluni àti Benjamini; 4Dani àti Naftali; Gadi àti Aṣeri. 5Àwọn ìran Jakọbu sì jẹ́ àádọ́rin ní àpapọ̀; Josẹfu sì ti wà ní Ejibiti. 6Wàyí o, Josẹfu àti gbogbo àwọn arákùnrin rẹ̀ àti gbogbo ìran náà kú, 7ṣùgbọ́n àwọn ará Israẹli ń bí sí i, wọ́n ń pọ̀ sí i gidigidi, wọ́n kò sì ní òǹkà tí ó fi jẹ́ pé wọ́n kún ilẹ̀ náà.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.