Native Bible

Exodus 1:3 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Isakari, Sebuluni àti Benjamini;

Exodus 1:3 in English

Exodus 1:3 · Berean Standard Bible

Issachar, Zebulun, and Benjamin;

Context

1Ìwọ̀nyí ni àwọn orúkọ ọmọ Israẹli tí wọ́n bá Jakọbu lọ sí Ejibiti, ẹnìkọ̀ọ̀kan pẹ̀lú ìdílé rẹ̀: 2Reubeni, Simeoni, Lefi àti Juda; 3Isakari, Sebuluni àti Benjamini; 4Dani àti Naftali; Gadi àti Aṣeri. 5Àwọn ìran Jakọbu sì jẹ́ àádọ́rin ní àpapọ̀; Josẹfu sì ti wà ní Ejibiti.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.