Native Bible

Exodus 1:2 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Reubeni, Simeoni, Lefi àti Juda;

Exodus 1:2 in English

Exodus 1:2 · Berean Standard Bible

Reuben, Simeon, Levi, and Judah;

Context

1Ìwọ̀nyí ni àwọn orúkọ ọmọ Israẹli tí wọ́n bá Jakọbu lọ sí Ejibiti, ẹnìkọ̀ọ̀kan pẹ̀lú ìdílé rẹ̀: 2Reubeni, Simeoni, Lefi àti Juda; 3Isakari, Sebuluni àti Benjamini; 4Dani àti Naftali; Gadi àti Aṣeri.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.