1 Tẹsalonika 5:17
1 Thessalonians 5:17 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ẹ máa gbàdúrà nígbà gbogbo.
1 Thessalonians 5:17 in English
1 Thessalonians 5:17 · Berean Standard Bible
Pray without ceasing.
Context
15Ẹ rí i pé kò sí ẹni tí ó fi búburú san búburú, ṣùgbọ́n ẹ máa lépa èyí tí í ṣe rere láàrín ara yín àti sí ènìyàn gbogbo. 16Ẹ máa yọ̀ nígbà gbogbo. 17Ẹ máa gbàdúrà nígbà gbogbo. 18Ẹ máa dúpẹ́ nígbà gbogbo nínú ipòkípò tí o wù kí ẹ wà; nítorí pé, èyí ni ìfẹ́ Ọlọ́run fún yin nínú Kristi Jesu nítòótọ́. 19Ẹ má ṣe pa iná Ẹ̀mí Mímọ́.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.