1 Tẹsalonika 5:16
1 Thessalonians 5:16 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ẹ máa yọ̀ nígbà gbogbo.
1 Thessalonians 5:16 in English
1 Thessalonians 5:16 · Berean Standard Bible
Rejoice at all times.
Context
14Ẹ̀yin ará mi, ẹ kìlọ̀ fún àwọn ọ̀lẹ ti ó wà láàrín yín, ẹ gba àwọn tí ẹ̀rù ń bà ní ìyànjú, ẹ tọ́jú àwọn aláìlera pẹ̀lẹ́pẹ̀lẹ́, kí ẹ sì ní sùúrù pẹ̀lú gbogbo ènìyàn. 15Ẹ rí i pé kò sí ẹni tí ó fi búburú san búburú, ṣùgbọ́n ẹ máa lépa èyí tí í ṣe rere láàrín ara yín àti sí ènìyàn gbogbo. 16Ẹ máa yọ̀ nígbà gbogbo. 17Ẹ máa gbàdúrà nígbà gbogbo. 18Ẹ máa dúpẹ́ nígbà gbogbo nínú ipòkípò tí o wù kí ẹ wà; nítorí pé, èyí ni ìfẹ́ Ọlọ́run fún yin nínú Kristi Jesu nítòótọ́.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.