Native Bible

1 Thessalonians 5:19 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ẹ má ṣe pa iná Ẹ̀mí Mímọ́.

1 Thessalonians 5:19 in English

Context

17Ẹ máa gbàdúrà nígbà gbogbo. 18Ẹ máa dúpẹ́ nígbà gbogbo nínú ipòkípò tí o wù kí ẹ wà; nítorí pé, èyí ni ìfẹ́ Ọlọ́run fún yin nínú Kristi Jesu nítòótọ́. 19Ẹ má ṣe pa iná Ẹ̀mí Mímọ́. 20Ẹ má ṣe kẹ́gàn àwọn ti ń sọtẹ́lẹ̀. 21Ṣùgbọ́n ẹ dán gbogbo nǹkan wò. Ẹ di èyí tí ṣe òtítọ́ mú.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.