Native Bible

1 Thessalonians 5:21 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ṣùgbọ́n ẹ dán gbogbo nǹkan wò. Ẹ di èyí tí ṣe òtítọ́ mú.

1 Thessalonians 5:21 in English

1 Thessalonians 5:21 · Berean Standard Bible

but test all things. Hold fast to what is good.

Context

19Ẹ má ṣe pa iná Ẹ̀mí Mímọ́. 20Ẹ má ṣe kẹ́gàn àwọn ti ń sọtẹ́lẹ̀. 21Ṣùgbọ́n ẹ dán gbogbo nǹkan wò. Ẹ di èyí tí ṣe òtítọ́ mú. 22Ẹ yẹra fún ohunkóhun tí í ṣe ibi. 23Kí Ọlọ́run fúnra rẹ̀, Ọlọ́run àlàáfíà, sọ yín di mímọ́ pátápátá. Kí Ọlọ́run pa ẹ̀mí àti ọkàn pẹ̀lú ara yín mọ́ pátápátá ní àìlábùkù, títí di ìgbà wíwá Jesu Kristi Olúwa wa.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.