1 Ọba 4:8
1 Kings 4:8 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Orúkọ wọn ni wọ̀nyí: Bene-Huri ní ìlú olókè Efraimu.
1 Kings 4:8 in English
1 Kings 4:8 · Berean Standard Bible
and these were their names: Ben-hur in the hill country of Ephraim;
Context
6Ahiṣari ni olùtọ́jú ààfin;
Adoniramu ọmọ Abida ni ó ń ṣe olórí iṣẹ́-ìlú. 7Solomoni sì tún ní ìjòyè méjìlá lórí gbogbo agbègbè Israẹli, tí wọ́n ń pèsè oúnjẹ fún ọba àti agbo ilé rẹ̀. Olúkúlùkù ní láti pèsè fún oṣù kan ní ọdún. 8Orúkọ wọn ni wọ̀nyí:
Bene-Huri ní ìlú olókè Efraimu. 9Bene-Dekeri ní Makasi, Ṣaalbimu, Beti-Ṣemeṣi, àti Eloni Beti-Hanani; 10Bene-Hesedi, ní Aruboti (tirẹ̀ ni Soko àti gbogbo ilẹ̀ Heferi ń ṣe);
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.