1 Ọba 4:7
1 Kings 4:7 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Solomoni sì tún ní ìjòyè méjìlá lórí gbogbo agbègbè Israẹli, tí wọ́n ń pèsè oúnjẹ fún ọba àti agbo ilé rẹ̀. Olúkúlùkù ní láti pèsè fún oṣù kan ní ọdún.
1 Kings 4:7 in English
1 Kings 4:7 · Berean Standard Bible
Solomon had twelve governors over all Israel to provide food for the king and his household. Each one would arrange provisions for one month of the year,
Context
5Asariah ọmọ Natani ni olórí àwọn agbègbè;
Sabudu ọmọ Natani, àlùfáà àti olùgba ọba ní ìmọ̀ràn; 6Ahiṣari ni olùtọ́jú ààfin;
Adoniramu ọmọ Abida ni ó ń ṣe olórí iṣẹ́-ìlú. 7Solomoni sì tún ní ìjòyè méjìlá lórí gbogbo agbègbè Israẹli, tí wọ́n ń pèsè oúnjẹ fún ọba àti agbo ilé rẹ̀. Olúkúlùkù ní láti pèsè fún oṣù kan ní ọdún. 8Orúkọ wọn ni wọ̀nyí:
Bene-Huri ní ìlú olókè Efraimu. 9Bene-Dekeri ní Makasi, Ṣaalbimu, Beti-Ṣemeṣi, àti Eloni Beti-Hanani;
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.