1 Ọba 4:6
1 Kings 4:6 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ahiṣari ni olùtọ́jú ààfin; Adoniramu ọmọ Abida ni ó ń ṣe olórí iṣẹ́-ìlú.
1 Kings 4:6 in English
1 Kings 4:6 · Berean Standard Bible
Ahishar was in charge of the palace; and Adoniram * son of Abda was in charge of the forced labor.
Context
4Benaiah ọmọ Jehoiada ni olórí ogun;
Sadoku àti Abiatari ni àwọn àlùfáà; 5Asariah ọmọ Natani ni olórí àwọn agbègbè;
Sabudu ọmọ Natani, àlùfáà àti olùgba ọba ní ìmọ̀ràn; 6Ahiṣari ni olùtọ́jú ààfin;
Adoniramu ọmọ Abida ni ó ń ṣe olórí iṣẹ́-ìlú. 7Solomoni sì tún ní ìjòyè méjìlá lórí gbogbo agbègbè Israẹli, tí wọ́n ń pèsè oúnjẹ fún ọba àti agbo ilé rẹ̀. Olúkúlùkù ní láti pèsè fún oṣù kan ní ọdún. 8Orúkọ wọn ni wọ̀nyí:
Bene-Huri ní ìlú olókè Efraimu.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.