Native Bible

1 Kings 4:9 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Bene-Dekeri ní Makasi, Ṣaalbimu, Beti-Ṣemeṣi, àti Eloni Beti-Hanani;

1 Kings 4:9 in English

1 Kings 4:9 · Berean Standard Bible

Ben-deker in Makaz, in Shaalbim, in Beth-shemesh, and in Elon-beth-hanan;

Context

7Solomoni sì tún ní ìjòyè méjìlá lórí gbogbo agbègbè Israẹli, tí wọ́n ń pèsè oúnjẹ fún ọba àti agbo ilé rẹ̀. Olúkúlùkù ní láti pèsè fún oṣù kan ní ọdún. 8Orúkọ wọn ni wọ̀nyí: Bene-Huri ní ìlú olókè Efraimu. 9Bene-Dekeri ní Makasi, Ṣaalbimu, Beti-Ṣemeṣi, àti Eloni Beti-Hanani; 10Bene-Hesedi, ní Aruboti (tirẹ̀ ni Soko àti gbogbo ilẹ̀ Heferi ń ṣe); 11Bene-Abinadabu, ní Napoti (Dori; òun ni ó fẹ́ Tafati ọmọbìnrin Solomoni ní aya).

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.