1 Kronika 4:33
1 Chronicles 4:33 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
àti gbogbo ìletò wọn, tí ó wà yí ìlú náà ká, dé Baali. Àwọn wọ̀nyí ni ibùgbé wọn. Àti ìtàn ìdílé wọ́n.
1 Chronicles 4:33 in English
1 Chronicles 4:33 · Berean Standard Bible
and all their surrounding villages as far as Baal.* These were their settlements, and they kept a genealogical record:
Context
31Beti-Markaboti Hormah; Hasari Susimu, Beti-Biri àti Ṣaraimi. Àwọn wọ̀nyí ni ìlú wọn títí di ìgbà ọba Dafidi, 32agbègbè ìlú wọn ni Etamu, Aini, Rimoni, Tokeni, Aṣani àwọn ìlú márùn-ún, 33àti gbogbo ìletò wọn, tí ó wà yí ìlú náà ká, dé Baali. Àwọn wọ̀nyí ni ibùgbé wọn.
Àti ìtàn ìdílé wọ́n. 34Meṣobabu àti Jamleki,
Josa ọmọ Amasiah, 35Joẹli,
Jehu ọmọ Josibiah, ọmọ Seraiah, ọmọ Asieli,
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.