Native Bible

1 Chronicles 4:35 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Joẹli, Jehu ọmọ Josibiah, ọmọ Seraiah, ọmọ Asieli,

1 Chronicles 4:35 in English

1 Chronicles 4:35 · Berean Standard Bible

Joel, Jehu son of Joshibiah (son of Seraiah, son of Asiel),

Context

33àti gbogbo ìletò wọn, tí ó wà yí ìlú náà ká, dé Baali. Àwọn wọ̀nyí ni ibùgbé wọn. Àti ìtàn ìdílé wọ́n. 34Meṣobabu àti Jamleki, Josa ọmọ Amasiah, 35Joẹli, Jehu ọmọ Josibiah, ọmọ Seraiah, ọmọ Asieli, 36àti pẹ̀lú Elioenai, Jaakoba, Jeṣohaiah, Asaiah, Adieli, Jesimieli, Benaiah, 37àti Sisa ọmọ Ṣifi ọmọ Alloni, ọmọ Jedaiah, ọmọ Ṣimri ọmọ Ṣemaiah.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.