Native Bible

1 Chronicles 4:37 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

àti Sisa ọmọ Ṣifi ọmọ Alloni, ọmọ Jedaiah, ọmọ Ṣimri ọmọ Ṣemaiah.

1 Chronicles 4:37 in English

1 Chronicles 4:37 · Berean Standard Bible

and Ziza son of Shiphi (son of Allon, son of Jedaiah, son of Shimri, son of Shemaiah).

Context

35Joẹli, Jehu ọmọ Josibiah, ọmọ Seraiah, ọmọ Asieli, 36àti pẹ̀lú Elioenai, Jaakoba, Jeṣohaiah, Asaiah, Adieli, Jesimieli, Benaiah, 37àti Sisa ọmọ Ṣifi ọmọ Alloni, ọmọ Jedaiah, ọmọ Ṣimri ọmọ Ṣemaiah. 38Àwọn ọkùnrin tí a dárúkọ lókè yìí àwọn ni ìjòyè ìdílé wọn. Àwọn ìdílé sì pọ̀ sí i gidigidi, 39wọ́n sì lọ sí ojú ọ̀nà Gedori. Lọ títí dé ìlà-oòrùn àfonífojì láti wá koríko fún àwọn agbo ẹran wọn.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.