1 Kronika 4:34
1 Chronicles 4:34 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Meṣobabu àti Jamleki, Josa ọmọ Amasiah,
1 Chronicles 4:34 in English
1 Chronicles 4:34 · Berean Standard Bible
Meshobab, Jamlech, Joshah son of Amaziah,
Context
32agbègbè ìlú wọn ni Etamu, Aini, Rimoni, Tokeni, Aṣani àwọn ìlú márùn-ún, 33àti gbogbo ìletò wọn, tí ó wà yí ìlú náà ká, dé Baali. Àwọn wọ̀nyí ni ibùgbé wọn.
Àti ìtàn ìdílé wọ́n. 34Meṣobabu àti Jamleki,
Josa ọmọ Amasiah, 35Joẹli,
Jehu ọmọ Josibiah, ọmọ Seraiah, ọmọ Asieli, 36àti pẹ̀lú Elioenai, Jaakoba, Jeṣohaiah,
Asaiah, Adieli, Jesimieli, Benaiah,
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.