1 Kronika 4:32
1 Chronicles 4:32 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
agbègbè ìlú wọn ni Etamu, Aini, Rimoni, Tokeni, Aṣani àwọn ìlú márùn-ún,
1 Chronicles 4:32 in English
1 Chronicles 4:32 · Berean Standard Bible
And their villages were Etam, Ain, Rimmon, Tochen, and Ashan—five towns—
Context
30Betueli, Horma, Siklagi, 31Beti-Markaboti Hormah; Hasari Susimu, Beti-Biri àti Ṣaraimi. Àwọn wọ̀nyí ni ìlú wọn títí di ìgbà ọba Dafidi, 32agbègbè ìlú wọn ni Etamu, Aini, Rimoni, Tokeni, Aṣani àwọn ìlú márùn-ún, 33àti gbogbo ìletò wọn, tí ó wà yí ìlú náà ká, dé Baali. Àwọn wọ̀nyí ni ibùgbé wọn.
Àti ìtàn ìdílé wọ́n. 34Meṣobabu àti Jamleki,
Josa ọmọ Amasiah,
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.