1 Kronika 4:3
1 Chronicles 4:3 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Àwọn wọ̀nyí ni àwọn ọmọ Etamu: Jesreeli, Iṣima, Idbaṣi, orúkọ arábìnrin wọn sì ni Haseleponi
1 Chronicles 4:3 in English
1 Chronicles 4:3 · Berean Standard Bible
These were the sons * of Etam: Jezreel, Ishma, and Idbash. And their sister was named Hazzelelponi.
Context
1Àwọn ọmọ Juda:
Peresi, Hesroni, Karmi, Huri àti Ṣobali. 2Reaiah ọmọ Ṣobali ni baba Jahati, àti Jahati baba Ahumai àti Lahadi. Àwọn wọ̀nyí ni ẹ̀yà ará Sorati. 3Àwọn wọ̀nyí ni àwọn ọmọ Etamu:
Jesreeli, Iṣima, Idbaṣi, orúkọ arábìnrin wọn sì ni Haseleponi 4Penueli sì ni baba Gedori, àti Eseri baba Huṣa.
Àwọn wọ̀nyí ni ọmọ Huri, àkọ́bí Efrata àti baba Bẹtilẹhẹmu. 5Aṣihuri baba Tekoa sì ní aya méjì, Hela àti Naara.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.