Native Bible

1 Chronicles 4:5 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Aṣihuri baba Tekoa sì ní aya méjì, Hela àti Naara.

1 Chronicles 4:5 in English

1 Chronicles 4:5 · Berean Standard Bible

Ashhur the father of Tekoa had two wives, Helah and Naarah.

Context

3Àwọn wọ̀nyí ni àwọn ọmọ Etamu: Jesreeli, Iṣima, Idbaṣi, orúkọ arábìnrin wọn sì ni Haseleponi 4Penueli sì ni baba Gedori, àti Eseri baba Huṣa. Àwọn wọ̀nyí ni ọmọ Huri, àkọ́bí Efrata àti baba Bẹtilẹhẹmu. 5Aṣihuri baba Tekoa sì ní aya méjì, Hela àti Naara. 6Naara sì bí Ahussamu, Heferi Temeni àti Haaṣtari. Àwọn wọ̀nyí sì ni àwọn ọmọ Naara. 7Àwọn ọmọ Hela: Sereti Sohari, Etani,

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.