Native Bible

1 Chronicles 4:7 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Àwọn ọmọ Hela: Sereti Sohari, Etani,

1 Chronicles 4:7 in English

1 Chronicles 4:7 · Berean Standard Bible

The sons of Helah were Zereth, Zohar,* Ethnan,

Context

5Aṣihuri baba Tekoa sì ní aya méjì, Hela àti Naara. 6Naara sì bí Ahussamu, Heferi Temeni àti Haaṣtari. Àwọn wọ̀nyí sì ni àwọn ọmọ Naara. 7Àwọn ọmọ Hela: Sereti Sohari, Etani, 8àti Kosi ẹni tí ó jẹ́ baba Anubu àti Sobeba àti ti àwọn ẹ̀yà Aharheli ọmọ Harumu. 9Jabesi sì ní ọlá ju àwọn ẹ̀gbọ́n rẹ̀ ọkùnrin lọ. Ìyá rẹ̀ sì sọ ọ́ ní Jabesi wí pé, “Mo bí i nínú ìpọ́njú.”

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.