Native Bible

1 Chronicles 4:1 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Àwọn ọmọ Juda: Peresi, Hesroni, Karmi, Huri àti Ṣobali.

1 Chronicles 4:1 in English

1 Chronicles 4:1 · Berean Standard Bible

The descendants of Judah: Perez, Hezron, Carmi, Hur, and Shobal.

Context

1Àwọn ọmọ Juda: Peresi, Hesroni, Karmi, Huri àti Ṣobali. 2Reaiah ọmọ Ṣobali ni baba Jahati, àti Jahati baba Ahumai àti Lahadi. Àwọn wọ̀nyí ni ẹ̀yà ará Sorati. 3Àwọn wọ̀nyí ni àwọn ọmọ Etamu: Jesreeli, Iṣima, Idbaṣi, orúkọ arábìnrin wọn sì ni Haseleponi

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.