1 Kronika 4:2
1 Chronicles 4:2 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Reaiah ọmọ Ṣobali ni baba Jahati, àti Jahati baba Ahumai àti Lahadi. Àwọn wọ̀nyí ni ẹ̀yà ará Sorati.
1 Chronicles 4:2 in English
1 Chronicles 4:2 · Berean Standard Bible
Reaiah son of Shobal was the father of Jahath, and Jahath was the father of Ahumai and Lahad. These were the clans of the Zorathites.
Context
1Àwọn ọmọ Juda:
Peresi, Hesroni, Karmi, Huri àti Ṣobali. 2Reaiah ọmọ Ṣobali ni baba Jahati, àti Jahati baba Ahumai àti Lahadi. Àwọn wọ̀nyí ni ẹ̀yà ará Sorati. 3Àwọn wọ̀nyí ni àwọn ọmọ Etamu:
Jesreeli, Iṣima, Idbaṣi, orúkọ arábìnrin wọn sì ni Haseleponi 4Penueli sì ni baba Gedori, àti Eseri baba Huṣa.
Àwọn wọ̀nyí ni ọmọ Huri, àkọ́bí Efrata àti baba Bẹtilẹhẹmu.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.