Native Bible

1 Chronicles 3:8 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Eliṣama, Eliada àti Elifeleti mẹ́sàn-án ni wọ́n.

1 Chronicles 3:8 in English

1 Chronicles 3:8 · Berean Standard Bible

Elishama, Eliada, and Eliphelet—nine in all.

Context

6Ibhari sì wà pẹ̀lú, Eliṣama, Elifeleti, 7Noga, Nefegi, Jafia, 8Eliṣama, Eliada àti Elifeleti mẹ́sàn-án ni wọ́n. 9Àwọn wọ̀nyí ni àwọn ọmọ Dafidi yàtọ̀ sí àwọn ọmọ tí àlè bí fún un. Tamari sì ni arábìnrin wọn. 10Ọmọ Solomoni ni Rehoboamu, Abijah ọmọ rẹ̀, Asa ọmọ rẹ̀, Jehoṣafati ọmọ rẹ̀,

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.