Native Bible

1 Chronicles 3:6 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ibhari sì wà pẹ̀lú, Eliṣama, Elifeleti,

1 Chronicles 3:6 in English

1 Chronicles 3:6 · Berean Standard Bible

David’s other sons were Ibhar,* Elishua,* Eliphelet,

Context

4Àwọn mẹ́fà wọ̀nyí ni a bí fún Dafidi ni Hebroni, níbi tí ó ti jẹ ọba fún ọdún méje àti oṣù mẹ́fà. Dafidi sì jẹ ọba ní Jerusalẹmu fún ọdún mẹ́tàlélọ́gbọ̀n. 5Wọ̀nyí ni ọmọ wẹ́wẹ́ tí a bí fún un ní Jerusalẹmu: Ṣimea, Ṣobabu, Natani àti Solomoni. Àwọn mẹ́rin wọ̀nyí sì ni a bí láti ọ̀dọ̀ Bati-Ṣua ọmọbìnrin Ammieli. 6Ibhari sì wà pẹ̀lú, Eliṣama, Elifeleti, 7Noga, Nefegi, Jafia, 8Eliṣama, Eliada àti Elifeleti mẹ́sàn-án ni wọ́n.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.