1 Kronika 3:7
1 Chronicles 3:7 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Noga, Nefegi, Jafia,
1 Chronicles 3:7 in English
1 Chronicles 3:7 · Berean Standard Bible
Nogah, Nepheg, Japhia,
Context
5Wọ̀nyí ni ọmọ wẹ́wẹ́ tí a bí fún un ní Jerusalẹmu:
Ṣimea, Ṣobabu, Natani àti Solomoni. Àwọn mẹ́rin wọ̀nyí sì ni a bí láti ọ̀dọ̀ Bati-Ṣua ọmọbìnrin Ammieli. 6Ibhari sì wà pẹ̀lú, Eliṣama, Elifeleti, 7Noga, Nefegi, Jafia, 8Eliṣama, Eliada àti Elifeleti mẹ́sàn-án ni wọ́n. 9Àwọn wọ̀nyí ni àwọn ọmọ Dafidi yàtọ̀ sí àwọn ọmọ tí àlè bí fún un. Tamari sì ni arábìnrin wọn.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.