1 Kronika 3:9
1 Chronicles 3:9 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Àwọn wọ̀nyí ni àwọn ọmọ Dafidi yàtọ̀ sí àwọn ọmọ tí àlè bí fún un. Tamari sì ni arábìnrin wọn.
1 Chronicles 3:9 in English
1 Chronicles 3:9 · Berean Standard Bible
These were all the sons of David, besides the sons by his concubines. And Tamar was their sister.
Context
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.