1 Kronika 23:16
1 Chronicles 23:16 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Àwọn ọmọ Gerṣomu: Ṣubaeli sì ni alákọ́kọ́.
1 Chronicles 23:16 in English
1 Chronicles 23:16 · Berean Standard Bible
The descendants of Gershom: Shebuel was the first.
Context
14Àwọn ọmọ Mose ènìyàn Ọlọ́run ni wọ́n kà gẹ́gẹ́ bí apá kan ẹ̀yà Lefi. 15Àwọn ọmọ Mose:
Gerṣomu àti Elieseri. 16Àwọn ọmọ Gerṣomu:
Ṣubaeli sì ni alákọ́kọ́. 17Àwọn ọmọ Elieseri:
Rehabiah sì ni ẹni àkọ́kọ́.
Elieseri kò sì tún ní ọmọ mìíràn, ṣùgbọ́n àwọn ọmọ Rehabiah wọ́n sì pọ̀ níye. 18Àwọn ọmọ Isari:
Ṣelomiti sì ni ẹni àkọ́kọ́.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.