1 Kronika 23:18
1 Chronicles 23:18 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Àwọn ọmọ Isari: Ṣelomiti sì ni ẹni àkọ́kọ́.
1 Chronicles 23:18 in English
1 Chronicles 23:18 · Berean Standard Bible
The sons of Izhar: Shelomith was the first.
Context
16Àwọn ọmọ Gerṣomu:
Ṣubaeli sì ni alákọ́kọ́. 17Àwọn ọmọ Elieseri:
Rehabiah sì ni ẹni àkọ́kọ́.
Elieseri kò sì tún ní ọmọ mìíràn, ṣùgbọ́n àwọn ọmọ Rehabiah wọ́n sì pọ̀ níye. 18Àwọn ọmọ Isari:
Ṣelomiti sì ni ẹni àkọ́kọ́. 19Àwọn ọmọ Hebroni:
Jeriah sì ni ẹni àkọ́kọ́, Amariah sì ni ẹni ẹ̀ẹ̀kejì,
Jahasieli sì ni ẹ̀ẹ̀kẹ́ta àti Jekameamu ẹ̀ẹ̀kẹrin. 20Àwọn ọmọ Usieli:
Mika ni àkọ́kọ́ àti Iṣiah ẹ̀ẹ̀kejì.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.