Native Bible

1 Chronicles 23:17 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Àwọn ọmọ Elieseri: Rehabiah sì ni ẹni àkọ́kọ́. Elieseri kò sì tún ní ọmọ mìíràn, ṣùgbọ́n àwọn ọmọ Rehabiah wọ́n sì pọ̀ níye.

1 Chronicles 23:17 in English

1 Chronicles 23:17 · Berean Standard Bible

The descendants of Eliezer: Rehabiah was the first. Eliezer did not have any other sons, but the sons of Rehabiah were very numerous.

Context

15Àwọn ọmọ Mose: Gerṣomu àti Elieseri. 16Àwọn ọmọ Gerṣomu: Ṣubaeli sì ni alákọ́kọ́. 17Àwọn ọmọ Elieseri: Rehabiah sì ni ẹni àkọ́kọ́. Elieseri kò sì tún ní ọmọ mìíràn, ṣùgbọ́n àwọn ọmọ Rehabiah wọ́n sì pọ̀ níye. 18Àwọn ọmọ Isari: Ṣelomiti sì ni ẹni àkọ́kọ́. 19Àwọn ọmọ Hebroni: Jeriah sì ni ẹni àkọ́kọ́, Amariah sì ni ẹni ẹ̀ẹ̀kejì, Jahasieli sì ni ẹ̀ẹ̀kẹ́ta àti Jekameamu ẹ̀ẹ̀kẹrin.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.