Native Bible

1 Chronicles 23:14 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Àwọn ọmọ Mose ènìyàn Ọlọ́run ni wọ́n kà gẹ́gẹ́ bí apá kan ẹ̀yà Lefi.

1 Chronicles 23:14 in English

1 Chronicles 23:14 · Berean Standard Bible

As for Moses the man of God, his sons were named among the tribe of Levi.

Context

12Àwọn ọmọ Kohati: Amramu, Isari, Hebroni àti Usieli mẹ́rin ni gbogbo wọn. 13Àwọn ọmọ Amramu. Aaroni àti Mose. A sì ya Aaroni sọ́tọ̀ òun àti àwọn ọmọ rẹ̀ títí láéláé, láti kọjú sí ohun mímọ́ jùlọ, láti fi rú ẹbọ sísun níwájú Olúwa, láti máa ṣe òjíṣẹ́ níwájú rẹ̀ àti láti kéde ìbùkún ní orúkọ rẹ̀ títí láéláé. 14Àwọn ọmọ Mose ènìyàn Ọlọ́run ni wọ́n kà gẹ́gẹ́ bí apá kan ẹ̀yà Lefi. 15Àwọn ọmọ Mose: Gerṣomu àti Elieseri. 16Àwọn ọmọ Gerṣomu: Ṣubaeli sì ni alákọ́kọ́.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.