1 Kronika 1:19
1 Chronicles 1:19 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Eberi sì bí ọmọ méjì: ọ̀kan ń jẹ́ Pelegi, nítorí ní ìgbà ọjọ́ rẹ̀ ni ilẹ̀ ya; orúkọ arákùnrin rẹ̀ ni Joktani.
1 Chronicles 1:19 in English
1 Chronicles 1:19 · Berean Standard Bible
Two sons were born to Eber: One was named Peleg,* because in his days the earth was divided, and his brother was named Joktan.
Context
17Àwọn ọmọ Ṣemu ni:
Elamu, Aṣuri, Arfakṣadi, Ludi àti Aramu.
Àwọn ọmọ Aramu:
Usi, Huli, Geteri, àti Meṣeki. 18Arfakṣadi sì bí Ṣela,
Ṣela sì bí Eberi. 19Eberi sì bí ọmọ méjì:
ọ̀kan ń jẹ́ Pelegi, nítorí ní ìgbà ọjọ́ rẹ̀ ni ilẹ̀ ya; orúkọ arákùnrin rẹ̀ ni Joktani. 20Joktani sì bí
Almodadi, Ṣelefi, Hasarmafeti, Jera. 21Hadoramu, Usali, Dikla,
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.