Native Bible

1 Chronicles 1:17 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Àwọn ọmọ Ṣemu ni: Elamu, Aṣuri, Arfakṣadi, Ludi àti Aramu. Àwọn ọmọ Aramu: Usi, Huli, Geteri, àti Meṣeki.

1 Chronicles 1:17 in English

1 Chronicles 1:17 · Berean Standard Bible

The sons of Shem: Elam, Asshur, Arphaxad, Lud, and Aram. The sons of Aram: * Uz, Hul, Gether, and Meshech.*

Context

15àti àwọn ará Hifi, àti àwọn ará Arki, àti àwọn ará Sini, 16àti àwọn ará Arfadi, àti àwọn ará Semari, àti àwọn ará Hamati. 17Àwọn ọmọ Ṣemu ni: Elamu, Aṣuri, Arfakṣadi, Ludi àti Aramu. Àwọn ọmọ Aramu: Usi, Huli, Geteri, àti Meṣeki. 18Arfakṣadi sì bí Ṣela, Ṣela sì bí Eberi. 19Eberi sì bí ọmọ méjì: ọ̀kan ń jẹ́ Pelegi, nítorí ní ìgbà ọjọ́ rẹ̀ ni ilẹ̀ ya; orúkọ arákùnrin rẹ̀ ni Joktani.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.