Native Bible

1 Chronicles 1:18 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Arfakṣadi sì bí Ṣela, Ṣela sì bí Eberi.

1 Chronicles 1:18 in English

1 Chronicles 1:18 · Berean Standard Bible

Arphaxad was the father of Shelah, and Shelah was the father of Eber.

Context

16àti àwọn ará Arfadi, àti àwọn ará Semari, àti àwọn ará Hamati. 17Àwọn ọmọ Ṣemu ni: Elamu, Aṣuri, Arfakṣadi, Ludi àti Aramu. Àwọn ọmọ Aramu: Usi, Huli, Geteri, àti Meṣeki. 18Arfakṣadi sì bí Ṣela, Ṣela sì bí Eberi. 19Eberi sì bí ọmọ méjì: ọ̀kan ń jẹ́ Pelegi, nítorí ní ìgbà ọjọ́ rẹ̀ ni ilẹ̀ ya; orúkọ arákùnrin rẹ̀ ni Joktani. 20Joktani sì bí Almodadi, Ṣelefi, Hasarmafeti, Jera.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.