Native Bible

1 Chronicles 1:21 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Hadoramu, Usali, Dikla,

1 Chronicles 1:21 in English

Context

19Eberi sì bí ọmọ méjì: ọ̀kan ń jẹ́ Pelegi, nítorí ní ìgbà ọjọ́ rẹ̀ ni ilẹ̀ ya; orúkọ arákùnrin rẹ̀ ni Joktani. 20Joktani sì bí Almodadi, Ṣelefi, Hasarmafeti, Jera. 21Hadoramu, Usali, Dikla, 22Ebali, Abimaeli, Ṣeba. 23Ofiri, Hafila, àti Jobabu. Gbogbo àwọn wọ̀nyí ni ọmọ Joktani.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.