Saamu 90:3
Psalms 90:3 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ìwọ yí ènìyàn padà sí erùpẹ̀, wí pé, “Padà sí erùpẹ̀, ìwọ ọmọ ènìyàn.”
Psalms 90:3 in English
Psalms 90:3 · Berean Standard Bible
You return man to dust, saying, “Return, O sons of mortals.”
Context
1Olúwa, ìwọ ti jẹ́ ibùgbé wa ní gbogbo ìran dé ìran. 2Kí a tó bí àwọn òkè ńlá
àti kí ìwọ tó dá ilẹ̀ àti ayé,
láti ayérayé dé ayérayé ìwọ ni Ọlọ́run. 3Ìwọ yí ènìyàn padà sí erùpẹ̀,
wí pé, “Padà sí erùpẹ̀, ìwọ ọmọ ènìyàn.” 4Nítorí pé ìgbà tí ẹgbẹ̀rún (1,000) ọdún bá kọjá lójú rẹ,
bí àná ni ó rí, bí ìgbà ìṣọ́ kan lóru. 5Ìwọ gbá ènìyàn dànù nínú oorun ikú;
wọ́n dàbí koríko tuntun ní òwúrọ̀.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.