Native Bible

Psalms 90:1 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Olúwa, ìwọ ti jẹ́ ibùgbé wa ní gbogbo ìran dé ìran.

Psalms 90:1 in English

Psalms 90:1 · Berean Standard Bible

Lord, You have been our dwelling place through all generations.

Context

1Olúwa, ìwọ ti jẹ́ ibùgbé wa ní gbogbo ìran dé ìran. 2Kí a tó bí àwọn òkè ńlá àti kí ìwọ tó dá ilẹ̀ àti ayé, láti ayérayé dé ayérayé ìwọ ni Ọlọ́run. 3Ìwọ yí ènìyàn padà sí erùpẹ̀, wí pé, “Padà sí erùpẹ̀, ìwọ ọmọ ènìyàn.”

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.