Saamu 90:5
Psalms 90:5 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ìwọ gbá ènìyàn dànù nínú oorun ikú; wọ́n dàbí koríko tuntun ní òwúrọ̀.
Psalms 90:5 in English
Psalms 90:5 · Berean Standard Bible
You whisk them away in their sleep; they are like the new grass of the morning—
Context
3Ìwọ yí ènìyàn padà sí erùpẹ̀,
wí pé, “Padà sí erùpẹ̀, ìwọ ọmọ ènìyàn.” 4Nítorí pé ìgbà tí ẹgbẹ̀rún (1,000) ọdún bá kọjá lójú rẹ,
bí àná ni ó rí, bí ìgbà ìṣọ́ kan lóru. 5Ìwọ gbá ènìyàn dànù nínú oorun ikú;
wọ́n dàbí koríko tuntun ní òwúrọ̀. 6Lóòtítọ́, ní òwúrọ̀, ó yọ tuntun
ní àṣálẹ́ ni yóò gbẹ, tí yóò sì rẹ̀ dànù. 7A pa wá run nípa ìbínú rẹ
nípa ìbínú rẹ ara kò rọ̀ wá.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.