Saamu 87:3
Psalms 87:3 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ohun ológo ni a sọ nípa rẹ̀, ìlú Ọlọ́run,
Psalms 87:3 in English
Psalms 87:3 · Berean Standard Bible
Glorious things are ascribed to you, O city of God. Selah
Context
1Ó ti fi ìpìlẹ̀ rẹ̀ sọlẹ̀ sórí òkè mímọ́; 2Olúwa fẹ́ràn ẹnu-ọ̀nà Sioni
ju gbogbo ibùgbé Jakọbu lọ. 3Ohun ológo ni a sọ nípa rẹ̀,
ìlú Ọlọ́run, 4“Èmi ó dárúkọ Rahabu àti Babeli
láàrín àwọn tí ó jẹ́wọ́ mi:
Filistia pẹ̀lú, àti Tire, pẹ̀lú Kuṣi,
yóò sọ pé, ‘Èyí ni a bí ní Sioni.’ ” 5Nítòótọ́, ti Sioni ni a ó sọ,
“Eléyìí àti eléyìí ni a bí nínú rẹ̀,
àti Ọlọ́run Ọ̀gá-ògo ni yóò fìdí rẹ̀ múlẹ̀.”
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.