Native Bible

Psalms 87:2 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Olúwa fẹ́ràn ẹnu-ọ̀nà Sioni ju gbogbo ibùgbé Jakọbu lọ.

Psalms 87:2 in English

Psalms 87:2 · Berean Standard Bible

The LORD loves the gates of Zion more than all the dwellings of Jacob.

Context

1Ó ti fi ìpìlẹ̀ rẹ̀ sọlẹ̀ sórí òkè mímọ́; 2Olúwa fẹ́ràn ẹnu-ọ̀nà Sioni ju gbogbo ibùgbé Jakọbu lọ. 3Ohun ológo ni a sọ nípa rẹ̀, ìlú Ọlọ́run, 4“Èmi ó dárúkọ Rahabu àti Babeli láàrín àwọn tí ó jẹ́wọ́ mi: Filistia pẹ̀lú, àti Tire, pẹ̀lú Kuṣi, yóò sọ pé, ‘Èyí ni a bí ní Sioni.’ ”

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.