Saamu 78:66
Psalms 78:66 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ó kọlu àwọn ọ̀tá rẹ̀ padà; ó fi wọn sínú ìtìjú ayérayé.
Psalms 78:66 in English
Psalms 78:66 · Berean Standard Bible
He beat back His foes; He put them to everlasting shame.
Context
64àfi àlùfáà wọn fún idà,
àwọn opó wọn kò sì le è sọkún. 65Olúwa sì jí gẹ́gẹ́ bí ẹni ojú oorun,
gẹ́gẹ́ bí ọkùnrin ti i jí kúrò nínú ìraníyè ọtí. 66Ó kọlu àwọn ọ̀tá rẹ̀ padà;
ó fi wọn sínú ìtìjú ayérayé. 67Nígbà náà ni ó kọ́ àgọ́ Josẹfu,
kò sì yan ẹ̀yà Efraimu, 68ṣùgbọ́n ó yan ẹ̀yà Juda,
òkè Sioni, èyí tí ó fẹ́ràn.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.