Saamu 78:64
Psalms 78:64 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
àfi àlùfáà wọn fún idà, àwọn opó wọn kò sì le è sọkún.
Psalms 78:64 in English
Psalms 78:64 · Berean Standard Bible
His priests fell by the sword, but their widows could not lament.
Context
62Ó fi àwọn ènìyàn rẹ̀ lé idà lọ́wọ́,
ó sì bínú sí àwọn ohun ìní rẹ̀. 63Iná run àwọn ọ̀dọ́mọkùnrin wọn,
àwọn ọmọbìnrin wọn kò sì ní orin ìgbéyàwó: 64àfi àlùfáà wọn fún idà,
àwọn opó wọn kò sì le è sọkún. 65Olúwa sì jí gẹ́gẹ́ bí ẹni ojú oorun,
gẹ́gẹ́ bí ọkùnrin ti i jí kúrò nínú ìraníyè ọtí. 66Ó kọlu àwọn ọ̀tá rẹ̀ padà;
ó fi wọn sínú ìtìjú ayérayé.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.