Native Bible

Psalms 73:4 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Wọn kò ṣe wàhálà; ara wọn mókun wọn sì lágbára.

Psalms 73:4 in English

Psalms 73:4 · Berean Standard Bible

They have no struggle in their death; their bodies are well-fed.

Context

2Ṣùgbọ́n bí ó ṣe ti èmi, ẹsẹ̀ mi ti yẹ̀ tán; ìrìn mi fẹ́rẹ̀ yọ̀ tán. 3Nítorí èmi ń ṣe ìlara àwọn tó ń ṣe féfé nígbà tí mo bá rí àlàáfíà àwọn ènìyàn búburú. 4Wọn kò ṣe wàhálà; ara wọn mókun wọn sì lágbára. 5Wọn kò ní ìpín nínú àjàgà tó ń ṣẹlẹ̀ sí ènìyàn; a kò pọ́n wọn lójú nípa ẹlòmíràn. 6Ìgbéraga ni ọ̀ṣọ́ ọrùn wọn; ìwà ipá bò wọ́n mọ́lẹ̀ bí aṣọ.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.