Native Bible

Psalms 73:2 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ṣùgbọ́n bí ó ṣe ti èmi, ẹsẹ̀ mi ti yẹ̀ tán; ìrìn mi fẹ́rẹ̀ yọ̀ tán.

Psalms 73:2 in English

Psalms 73:2 · Berean Standard Bible

But as for me, my feet had almost stumbled; my steps had nearly slipped.

Context

1Nítòótọ́ Ọlọ́run dára fún Israẹli, fún àwọn ọlọ́kàn funfun. 2Ṣùgbọ́n bí ó ṣe ti èmi, ẹsẹ̀ mi ti yẹ̀ tán; ìrìn mi fẹ́rẹ̀ yọ̀ tán. 3Nítorí èmi ń ṣe ìlara àwọn tó ń ṣe féfé nígbà tí mo bá rí àlàáfíà àwọn ènìyàn búburú. 4Wọn kò ṣe wàhálà; ara wọn mókun wọn sì lágbára.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.