Native Bible

Psalms 73:15 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Bí mo bá wí pé, “Èmi ó wí báyìí,” èmi ó ṣẹ̀ sí ìran àwọn ọmọ rẹ̀.

Psalms 73:15 in English

Psalms 73:15 · Berean Standard Bible

If I had said, “I will speak this way,” then I would have betrayed Your children.

Context

13Nítòótọ́ nínú asán ni mo pa ọkàn mi mọ́; nínú asán ni mo wẹ ọwọ́ mi ní àìlẹ́ṣẹ̀. 14Ní gbogbo ọjọ́ ni a ń yọ mí lẹ́nu; a sì ń jẹ mí ní yà ní gbogbo òwúrọ̀. 15Bí mo bá wí pé, “Èmi ó wí báyìí,” èmi ó ṣẹ̀ sí ìran àwọn ọmọ rẹ̀. 16Nígbà tí mo gbìyànjú láti mọ èyí, Ó jẹ́ ìnilára fún mi, 17títí mo fi wọ ibi mímọ́ Ọlọ́run; nígbà náà ni òye ìgbẹ̀yìn wọn yé mi.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.